Léfítíkù 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè tí màá lé jáde kúrò níwájú yín;+ torí wọ́n ti ṣe gbogbo nǹkan yìí, mo sì kórìíra wọn.+
23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè tí màá lé jáde kúrò níwájú yín;+ torí wọ́n ti ṣe gbogbo nǹkan yìí, mo sì kórìíra wọn.+