-
Diutarónómì 8:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Bíi ti àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa pa run níwájú yín, bẹ́ẹ̀ lẹ ṣe máa pa run, torí ẹ ò fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín.+
-