ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 6:33-35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Bẹ́ẹ̀ náà ni ó ṣe fi igi ahóyaya ṣe férémù ilẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì,* igun rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin sì dọ́gba.* 34 Ó fi igi júnípà ṣe ilẹ̀kùn méjì. Ilẹ̀kùn àkọ́kọ́ ní awẹ́ méjì tó ṣeé pa dé, ilẹ̀kùn kejì sì ní awẹ́ méjì tó ṣeé pa dé.+ 35 Ó gbẹ́ àwọn kérúbù, igi ọ̀pẹ àti ìtànná òdòdó, ó sì fi wúrà fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ bo gbogbo wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́