2 Kíróníkà 32:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ Ọba Hẹsikáyà àti wòlíì Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì kò dákẹ́ àdúrà lórí ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n sì ń ké pe Ọlọ́run lókè ọ̀run pé kó ran àwọn lọ́wọ́.+
20 Àmọ́ Ọba Hẹsikáyà àti wòlíì Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì kò dákẹ́ àdúrà lórí ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n sì ń ké pe Ọlọ́run lókè ọ̀run pé kó ran àwọn lọ́wọ́.+