Àìsáyà 46:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Láti ìbẹ̀rẹ̀, mò ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀,Tipẹ́tipẹ́ ni mo sì ti ń sọ àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.+ Mo sọ pé, ‘Ìpinnu mi* máa dúró,+Màá sì ṣe ohunkóhun tó bá wù mí.’+
10 Láti ìbẹ̀rẹ̀, mò ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀,Tipẹ́tipẹ́ ni mo sì ti ń sọ àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.+ Mo sọ pé, ‘Ìpinnu mi* máa dúró,+Màá sì ṣe ohunkóhun tó bá wù mí.’+