Jónà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Gbéra, lọ sí Nínéfè+ ìlú ńlá náà, kí o sì kéde ìdájọ́ mi fún wọn, torí mo ti rí gbogbo ìwà burúkú wọn.”
2 “Gbéra, lọ sí Nínéfè+ ìlú ńlá náà, kí o sì kéde ìdájọ́ mi fún wọn, torí mo ti rí gbogbo ìwà burúkú wọn.”