-
Jòhánù 9:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ó dáhùn pé: “Ọkùnrin tí wọ́n ń pè ní Jésù ló po nǹkan kan, ó sì fi pa ojú mi, ó wá sọ fún mi pé, ‘Lọ wẹ̀ ní Sílóámù.’+ Mo wá lọ wẹ̀, mo sì ríran.”
-