-
2 Kíróníkà 32:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Níkẹyìn, Hẹsikáyà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín síbi ìgòkè tó wà níbi tí wọ́n sin àwọn ọmọ Dáfídì sí;+ gbogbo Júdà àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù sì yẹ́ ẹ sí nígbà ìsìnkú rẹ̀. Mánásè ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-