-
Jeremáyà 19:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí o sọ pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin ọba Júdà àti ẹ̀yin tó ń gbé Jerúsálẹ́mù. Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí:
“‘“Màá tó mú àjálù kan wá bá ibí yìí, etí ẹnikẹ́ni tó bá sì gbọ́ nípa rẹ̀ máa hó yee.
-