ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 24:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó dájú pé àṣẹ tí Jèhófà pa ló mú kí èyí ṣẹlẹ̀ sí Júdà, kí ó lè mú wọn kúrò níwájú rẹ̀+ nítorí gbogbo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí Mánásè dá+ 4 àti nítorí ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí ó ta sílẹ̀,+ torí ó ti fi ẹ̀jẹ̀ àwọn aláìṣẹ̀ kún Jerúsálẹ́mù, Jèhófà kò sì fẹ́ dárí jì wọ́n.+

  • Jeremáyà 2:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Kódà, ẹ̀jẹ̀ àwọn* aláìní tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ ti ta sí ọ láṣọ,+

      Kì í ṣe torí pé wọ́n ń fọ́lé ni o fi pa wọ́n;

      Síbẹ̀, mo ṣì rí ẹ̀jẹ̀ wọn lára gbogbo aṣọ rẹ.+

  • Mátíù 23:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 ẹ sì sọ pé, ‘Ká ní a wà láyé nígbà ayé àwọn baba ńlá wa ni, a ò ní lọ́wọ́ sí bí wọ́n ṣe ta ẹ̀jẹ̀ àwọn wòlíì sílẹ̀.’

  • Hébérù 11:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Wọ́n sọ wọ́n lókùúta,+ wọ́n dán wọn wò, wọ́n fi ayùn rẹ́ wọn sí méjì,* wọ́n fi idà pa wọ́n,+ wọ́n rìn kiri pẹ̀lú awọ àgùntàn àti awọ ewúrẹ́ lọ́rùn,+ nígbà tí wọ́n ṣaláìní, nínú ìpọ́njú,+ nígbà tí wọ́n hùwà àìdáa sí wọn;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́