2 Àwọn Ọba 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbàrà tí ọba gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ inú ìwé Òfin náà, ó fa aṣọ rẹ̀ ya.+