-
2 Kíróníkà 35:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Wọn ò ṣe irú Ìrékọjá bẹ́ẹ̀ rí ní Ísírẹ́lì láti ìgbà ayé wòlíì Sámúẹ́lì; bẹ́ẹ̀ ni kò sí ìkankan lára àwọn ọba Ísírẹ́lì tó ṣe irú Ìrékọjá tí Jòsáyà ṣe+ pẹ̀lú àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì àti gbogbo Júdà pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù. 19 Wọ́n ṣe Ìrékọjá yìí ní ọdún kejìdínlógún ìjọba Jòsáyà.
-