-
2 Kíróníkà 36:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ní ti ìyókù ìtàn Jèhóákímù àti àwọn ohun ìríra tí ó ṣe àti nǹkan búburú tí a mọ̀ nípa rẹ̀, wọ́n wà lákọsílẹ̀ nínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì àti ti Júdà; Jèhóákínì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.+
-