-
Jeremáyà 40:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ìgbà náà ni Jóhánánì ọmọ Káréà yọ́ ọ̀rọ̀ sọ fún Gẹdaláyà ní Mísípà pé: “Mo fẹ́ lọ pa Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà, ẹnikẹ́ni kò sì ní mọ̀. Kí ló dé tó fi máa pa ọ́,* tí gbogbo àwọn èèyàn Júdà tí wọ́n kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ á fi tú ká, tí àwọn tó ṣẹ́ kù ní Júdà á sì pa run?”
-