-
Mátíù 28:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Wò ó! Jésù pàdé wọn, ó sì sọ pé: “Ẹ ǹlẹ́ o!” Wọ́n sún mọ́ ọn, wọ́n di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú, wọ́n sì tẹrí ba* fún un.