ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 16:6-10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bí wọ́n ṣe wọlé, tí ó sì rí Élíábù,+ ó sọ pé: “Ó dájú pé ẹni àmì òróró Jèhófà ló dúró yìí.” 7 Ṣùgbọ́n Jèhófà sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Má wo ìrísí rẹ̀ àti bí ó ṣe ga tó,+ torí pé mo ti kọ̀ ọ́. Nítorí ọ̀nà tí èèyàn gbà ń wo nǹkan kọ́ ni Ọlọ́run gbà ń wo nǹkan, torí pé ohun tí ó bá hàn síta ni èèyàn ń rí, ṣùgbọ́n Jèhófà ń rí ohun tó wà nínú ọkàn.”+ 8 Jésè bá pe Ábínádábù,+ ó sì ní kí ó kọjá níwájú Sámúẹ́lì, àmọ́ ó sọ pé: “Jèhófà kò yan eléyìí náà.” 9 Lẹ́yìn náà, Jésè mú Ṣámà wá,+ ṣùgbọ́n ó sọ pé: “Jèhófà kò yan eléyìí náà.” 10 Nítorí náà, Jésè mú kí méje lára àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ kọjá níwájú Sámúẹ́lì, àmọ́ Sámúẹ́lì sọ fún Jésè pé: “Jèhófà kò yan ìkankan lára wọn.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́