1 Kíróníkà 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+
5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+