-
Ẹ́kísódù 17:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nígbà tí ọwọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í ro Mósè, wọ́n gbé òkúta kan sábẹ́ rẹ̀, ó sì jókòó lé e. Áárónì àti Húrì wá dúró sí ẹ̀gbẹ́ Mósè lọ́tùn-ún àti lósì, wọ́n bá a gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ọwọ́ rẹ̀ sì dúró gbọn-in títí oòrùn fi wọ̀.
-