Jẹ́nẹ́sísì 50:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jósẹ́fù rí ìran kẹta àwọn ọmọ+ Éfúrémù, pẹ̀lú àwọn ọmọ Mákírù,+ ọmọ Mánásè. Orúnkún Jósẹ́fù ni wọ́n bí wọn sí.* 1 Kíróníkà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn ọmọ Mánásè+ ni: Ásíríélì, tí wáhàrì* rẹ̀ ará Síríà bí. (Ó bí Mákírù+ bàbá Gílíádì.
23 Jósẹ́fù rí ìran kẹta àwọn ọmọ+ Éfúrémù, pẹ̀lú àwọn ọmọ Mákírù,+ ọmọ Mánásè. Orúnkún Jósẹ́fù ni wọ́n bí wọn sí.*