Nehemáyà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni àwọn ará Tékóà+ ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, àmọ́ àwọn olókìkí àárín wọn kò rẹ ara wọn sílẹ̀ láti ṣe nínú* iṣẹ́ àwọn ọ̀gá wọn.
5 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni àwọn ará Tékóà+ ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, àmọ́ àwọn olókìkí àárín wọn kò rẹ ara wọn sílẹ̀ láti ṣe nínú* iṣẹ́ àwọn ọ̀gá wọn.