-
2 Sámúẹ́lì 13:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Lẹ́yìn náà, Ábúsálómù pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ máa ṣọ́ Ámínónì, nígbà tí wáìnì bá ti ń mú inú rẹ̀ dùn, màá sọ fún yín pé, ‘Ẹ ṣá Ámínónì balẹ̀!’ Nígbà náà, kí ẹ pa á. Ẹ má bẹ̀rù. Ṣebí èmi ni mo pàṣẹ fún yín? Ẹ jẹ́ alágbára, kí ẹ sì ní ìgboyà.”
-
-
2 Sámúẹ́lì 13:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Àmọ́ Ábúsálómù sá, ó lọ sọ́dọ̀ Tálímáì+ ọmọ Ámíhúdù ọba Géṣúrì. Ọ̀pọ̀ ọjọ́ ni Dáfídì fi ṣọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀.
-
-
2 Sámúẹ́lì 18:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jóábù bá sọ pé: “Mi ò ní fi àkókò mi ṣòfò lọ́dọ̀ rẹ mọ́!” Torí náà, ó mú aṣóró* mẹ́ta, ó sì fi wọ́n gún ọkàn Ábúsálómù ní àgúnyọ nígbà tí ó ṣì wà láàyè ní àárín igi ńlá náà.
-