-
2 Kíróníkà 20:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Jèhóṣáfátì ń jọba lórí Júdà nìṣó. Ẹni ọdún márùndínlógójì (35) ni nígbà tó jọba, ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ásúbà ọmọ Ṣílíháì.+
-