1 Kíróníkà 2:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Àwọn ìdílé Kiriati-jéárímù ni àwọn Ítírì,+ àwọn Púútì, àwọn Ṣúmátì àti àwọn Míṣíráì. Inú àwọn yìí ni àwọn Sórátì+ àti àwọn ará Éṣítáólì+ ti wá.
53 Àwọn ìdílé Kiriati-jéárímù ni àwọn Ítírì,+ àwọn Púútì, àwọn Ṣúmátì àti àwọn Míṣíráì. Inú àwọn yìí ni àwọn Sórátì+ àti àwọn ará Éṣítáólì+ ti wá.