Diutarónómì 2:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Láti Áróérì,+ èyí tó wà ní etí Àfonífojì Áánónì, (títí kan ìlú tó wà ní àfonífojì náà), títí dé Gílíádì, kò sí ìlú tí apá wa ò ká. Gbogbo wọn ni Jèhófà Ọlọ́run wa fi lé wa lọ́wọ́.+
36 Láti Áróérì,+ èyí tó wà ní etí Àfonífojì Áánónì, (títí kan ìlú tó wà ní àfonífojì náà), títí dé Gílíádì, kò sí ìlú tí apá wa ò ká. Gbogbo wọn ni Jèhófà Ọlọ́run wa fi lé wa lọ́wọ́.+