-
Ẹ́kísódù 6:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn ọmọ Mérárì ni Máhílì àti Múṣì.
Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn.+
-
-
1 Kíróníkà 23:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ọmọ Mérárì ni Máhílì àti Múṣì.+ Àwọn ọmọ Máhílì ni Élíásárì àti Kíṣì.
-