-
1 Kíróníkà 15:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Dáfídì wá sọ fún àwọn olórí ọmọ Léfì pé kí wọ́n yan àwọn arákùnrin wọn tó jẹ́ akọrin láti máa fi ayọ̀ kọrin, kí wọ́n máa lo àwọn ohun ìkọrin, ìyẹn àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ pẹ̀lú síńbálì.*+
17 Torí náà, àwọn ọmọ Léfì yan Hémánì+ ọmọ Jóẹ́lì, lára àwọn arákùnrin rẹ̀, wọ́n yan Ásáfù+ ọmọ Berekáyà, lára àwọn ọmọ Mérárì tí wọ́n jẹ́ arákùnrin wọn, wọ́n yan Étánì+ ọmọ Kuṣáyà.
-