Jóṣúà 15:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ààlà náà yí láti Báálà gba apá ìwọ̀ oòrùn lọ sí Òkè Séírì, ó kọjá lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Òkè Jéárímù ní àríwá, ìyẹn Kẹ́sálónì, ó lọ sí Bẹti-ṣémẹ́ṣì,+ ó sì dé Tímúnà.+ Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.
10 Ààlà náà yí láti Báálà gba apá ìwọ̀ oòrùn lọ sí Òkè Séírì, ó kọjá lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Òkè Jéárímù ní àríwá, ìyẹn Kẹ́sálónì, ó lọ sí Bẹti-ṣémẹ́ṣì,+ ó sì dé Tímúnà.+
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.