Jóṣúà 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kèké mú ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì,+ wọ́n sì fi kèké pín* ìlú mẹ́tàlá (13) fún àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ àlùfáà Áárónì, látinú ìpín ẹ̀yà Júdà,+ ẹ̀yà Síméónì+ àti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì.+
4 Kèké mú ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì,+ wọ́n sì fi kèké pín* ìlú mẹ́tàlá (13) fún àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ àlùfáà Áárónì, látinú ìpín ẹ̀yà Júdà,+ ẹ̀yà Síméónì+ àti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì.+