-
Jóṣúà 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ó lọ láti Sárídì sápá ìlà oòrùn níbi tí oòrùn ti ń yọ dé ààlà Kisiloti-tábórì, ó dé Dábérátì,+ ó sì tún dé Jáfíà.
-
-
Jóṣúà 19:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Èyí ni ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Sébúlúnì ní ìdílé-ìdílé.+ Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-