-
Jẹ́nẹ́sísì 35:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn náà, wọ́n ṣí kúrò ní Bẹ́tẹ́lì. Nígbà tí ọ̀nà wọn ṣì jìn díẹ̀ sí Éfúrátì, Réṣẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í rọbí, ó sì nira fún un gan-an.
-