-
Nọ́ńbà 1:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ nínú ẹ̀yà Áṣérì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mọ́kànlélógójì ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (41,500).
-
-
Nọ́ńbà 26:47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Áṣérì, iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàléláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (53,400).+
-