-
Jóṣúà 19:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-
-
Jóṣúà 21:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Áíjálónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Gati-rímónì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́rin.
-