Jẹ́nẹ́sísì 10:26-29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Jókítánì bí Álímódádì, Ṣéléfì, Hásámáfétì, Jérà,+ 27 Hádórámù, Úsálì, Díkílà, 28 Óbálì, Ábímáélì, Ṣébà, 29 Ófírì,+ Háfílà àti Jóbábù; gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Jókítánì.
26 Jókítánì bí Álímódádì, Ṣéléfì, Hásámáfétì, Jérà,+ 27 Hádórámù, Úsálì, Díkílà, 28 Óbálì, Ábímáélì, Ṣébà, 29 Ófírì,+ Háfílà àti Jóbábù; gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Jókítánì.