-
1 Sámúẹ́lì 14:45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn náà sọ fún Sọ́ọ̀lù pé: “Ṣé ó yẹ kí Jónátánì kú, ẹni tó mú ìṣẹ́gun* ńlá+ wá fún Ísírẹ́lì? Kò ṣeé gbọ́ sétí! Bí Jèhófà ti wà láàyè, ẹyọ kan nínú irun orí rẹ̀ kò ní bọ́ sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run lọ́wọ́ sí gbogbo ohun tó ṣe lónìí yìí.”+ Bí àwọn èèyàn náà ṣe gba Jónátánì sílẹ̀* nìyẹn, kò sì kú.
-