-
1 Kíróníkà 9:39-44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Nérì+ bí Kíṣì; Kíṣì bí Sọ́ọ̀lù;+ Sọ́ọ̀lù bí Jónátánì,+ Maliki-ṣúà,+ Ábínádábù+ àti Eṣibáálì. 40 Ọmọ Jónátánì ni Meribu-báálì.+ Meribu-báálì bí Míkà.+ 41 Àwọn ọmọ Míkà ni Pítónì, Mélékì, Tááréà àti Áhásì. 42 Áhásì bí Járà; Járà bí Álémétì, Ásímáfẹ́tì àti Símírì. Símírì bí Mósà. 43 Mósà bí Bínéà àti Refáyà, ọmọ* rẹ̀ ni Éléásà, ọmọ rẹ̀ sì ni Ásélì. 44 Ásélì ní ọmọkùnrin mẹ́fà, orúkọ wọn ni Ásíríkámù, Bókérù, Íṣímáẹ́lì, Ṣearáyà, Ọbadáyà àti Hánánì. Gbogbo wọn ni ọmọ Ásélì.
-