-
1 Kíróníkà 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Orúkọ gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà nínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn, a sì kọ wọ́n sínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì. Àwọn ọmọ Júdà ni a sì kó lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì nítorí ìwà àìṣòótọ́+ wọn.
-