1 Sámúẹ́lì 20:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tí bàbá rẹ bá ṣàárò mi, kí o sọ fún un pé, ‘Dáfídì tọrọ àyè lọ́wọ́ mi pé òun fẹ́ sáré lọ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ìlú òun, torí pé ẹbọ ọdọọdún kan wà tí gbogbo ìdílé+ rẹ̀ máa rú níbẹ̀.’
6 Tí bàbá rẹ bá ṣàárò mi, kí o sọ fún un pé, ‘Dáfídì tọrọ àyè lọ́wọ́ mi pé òun fẹ́ sáré lọ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ìlú òun, torí pé ẹbọ ọdọọdún kan wà tí gbogbo ìdílé+ rẹ̀ máa rú níbẹ̀.’