1 Sámúẹ́lì 17:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ni akọgun kan bá jáde láti ibùdó àwọn Filísínì, Gòláyátì ni orúkọ rẹ̀,+ ará Gátì ni,+ gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà àti ìbú àtẹ́lẹwọ́ kan.*
4 Ni akọgun kan bá jáde láti ibùdó àwọn Filísínì, Gòláyátì ni orúkọ rẹ̀,+ ará Gátì ni,+ gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà àti ìbú àtẹ́lẹwọ́ kan.*