1 Kíróníkà 6:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ mú ẹbọ rú èéfín lórí pẹpẹ ẹbọ sísun+ àti lórí pẹpẹ tùràrí,+ wọ́n ń ṣe àwọn iṣẹ́ tó jẹ mọ́ àwọn ohun mímọ́ jù lọ, láti ṣe ètùtù fún Ísírẹ́lì,+ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ohun tí Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ pa láṣẹ.
49 Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ mú ẹbọ rú èéfín lórí pẹpẹ ẹbọ sísun+ àti lórí pẹpẹ tùràrí,+ wọ́n ń ṣe àwọn iṣẹ́ tó jẹ mọ́ àwọn ohun mímọ́ jù lọ, láti ṣe ètùtù fún Ísírẹ́lì,+ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ohun tí Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ pa láṣẹ.