1 Sámúẹ́lì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Odindi ogún (20) ọdún kọjá lẹ́yìn tí Àpótí náà ti dé Kiriati-jéárímù kí gbogbo ilé Ísírẹ́lì tó bẹ̀rẹ̀ sí í wá* Jèhófà.+
2 Odindi ogún (20) ọdún kọjá lẹ́yìn tí Àpótí náà ti dé Kiriati-jéárímù kí gbogbo ilé Ísírẹ́lì tó bẹ̀rẹ̀ sí í wá* Jèhófà.+