1 Sámúẹ́lì 14:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Áhíjà pé:+ “Gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ sún mọ́ tòsí!” (Torí pé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní àkókò yẹn.*)
18 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Áhíjà pé:+ “Gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ sún mọ́ tòsí!” (Torí pé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní àkókò yẹn.*)