-
2 Kíróníkà 5:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Gbàrà tí àwọn tó ń fun kàkàkí àti àwọn akọrin bẹ̀rẹ̀ sí í yin Jèhófà, tí wọ́n sì ń dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ohùn tó ṣọ̀kan, tí ìró kàkàkí àti síńbálì pẹ̀lú àwọn ohun ìkọrin míì ń dún sókè bí wọ́n ṣe ń yin Jèhófà, “nítorí ó jẹ́ ẹni rere; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì wà títí láé,”+ ni ìkùukùu+ bá kún inú ilé náà, ìyẹn ilé Jèhófà.
-