-
Àwọn Onídàájọ́ 4:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Dèbórà wá sọ fún Bárákì pé: “Gbéra, torí òní yìí ni Jèhófà máa fi Sísérà lé ọ lọ́wọ́. Ṣebí Jèhófà ń ṣáájú rẹ lọ?” Bárákì sì sọ̀ kalẹ̀ láti orí Òkè Tábórì pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin tó ń tẹ̀ lé e.
-