ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 16:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Lẹ́yìn náà, ó yan lára àwọn ọmọ Léfì láti máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí Jèhófà,+ kí wọ́n máa bọlá fún* Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí wọ́n máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, kí wọ́n sì máa yìn ín.

  • 1 Kíróníkà 16:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bẹnáyà àti Jáhásíẹ́lì tí wọ́n jẹ́ àlùfáà sì ń fun kàkàkí déédéé níwájú àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́