-
1 Kíróníkà 13:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ sì wà ní agbo ilé Obedi-édómù, oṣù mẹ́ta ló fi wà ní ilé rẹ̀, Jèhófà sì ń bù kún agbo ilé Obedi-édómù àti gbogbo ohun tó ní.+
-