Diutarónómì 28:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 “Tí o ò bá rí i pé o tẹ̀ lé gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin tí wọ́n kọ sínú ìwé+ yìí, tí o ò sì bẹ̀rù orúkọ+ ológo, tó ń bani lẹ́rù yìí tí Jèhófà+ Ọlọ́run rẹ ní, Nehemáyà 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn Jéṣúà, Kádímíélì, Bánì, Haṣabanéáyà, Ṣerebáyà, Hodáyà, Ṣebanáyà àti Petaháyà sọ pé: “Ẹ dìde, kí ẹ yin Jèhófà Ọlọ́run yín títí láé àti láéláé.*+ Kí wọ́n yin orúkọ rẹ ológo, èyí tí a gbé ga ju gbogbo ìbùkún àti ìyìn lọ. Sáàmù 148:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+
58 “Tí o ò bá rí i pé o tẹ̀ lé gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin tí wọ́n kọ sínú ìwé+ yìí, tí o ò sì bẹ̀rù orúkọ+ ológo, tó ń bani lẹ́rù yìí tí Jèhófà+ Ọlọ́run rẹ ní,
5 Àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn Jéṣúà, Kádímíélì, Bánì, Haṣabanéáyà, Ṣerebáyà, Hodáyà, Ṣebanáyà àti Petaháyà sọ pé: “Ẹ dìde, kí ẹ yin Jèhófà Ọlọ́run yín títí láé àti láéláé.*+ Kí wọ́n yin orúkọ rẹ ológo, èyí tí a gbé ga ju gbogbo ìbùkún àti ìyìn lọ.
13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+