-
Sáàmù 103:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àmọ́ ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ wà títí ayé*
Sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀+
Àti òdodo rẹ̀ sí àwọn ọmọ ọmọ wọn,+
-
17 Àmọ́ ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ wà títí ayé*
Sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀+
Àti òdodo rẹ̀ sí àwọn ọmọ ọmọ wọn,+