Jẹ́nẹ́sísì 36:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ Séírì ọmọ Hórì tí wọ́n ń gbé ilẹ̀+ náà nìyí: Lótánì, Ṣóbálì, Síbéónì, Ánáhì,+ 21 Díṣónì, Ésérì àti Díṣánì.+ Àwọn ni séríkí àwọn Hórì, àwọn ọmọ Séírì, ní ilẹ̀ Édómù.
20 Àwọn ọmọ Séírì ọmọ Hórì tí wọ́n ń gbé ilẹ̀+ náà nìyí: Lótánì, Ṣóbálì, Síbéónì, Ánáhì,+ 21 Díṣónì, Ésérì àti Díṣánì.+ Àwọn ni séríkí àwọn Hórì, àwọn ọmọ Séírì, ní ilẹ̀ Édómù.