2 Sámúẹ́lì 5:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí náà, Dáfídì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún un gẹ́lẹ́, ó sì pa àwọn Filísínì+ láti Gébà+ títí dé Gésérì.+
25 Torí náà, Dáfídì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún un gẹ́lẹ́, ó sì pa àwọn Filísínì+ láti Gébà+ títí dé Gésérì.+