Léfítíkù 19:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ fá* irun ẹ̀gbẹ́ orí yín tàbí kí ẹ ba eteetí irùngbọ̀n yín jẹ́.+